2021
Lançamento Livro The Ògbóni Fraternity Lagos – Nigeria
Kábíyèsí ba Ọba Adekunlé Aderonmu ira lançar livro no dia 04 de abril em lagos – Nigeria SINOPSE Kábíyèsí Ọba Adekunlé Aderonmu, Ọba Ògbóni Iwaṣhẹ Káàkiri Àgbáyé, Embaixador da Paz
Kábíyèsí ba Ọba Adekunlé Aderonmu ira lançar livro no dia 04 de abril em lagos – Nigeria SINOPSE Kábíyèsí Ọba Adekunlé Aderonmu, Ọba Ògbóni Iwaṣhẹ Káàkiri Àgbáyé, Embaixador da Paz
Olódùmarè, mo ji loni. Mo wo'gun merin aye.
Igun'kini, igun'keji, igun'keta, igun'kerin Olojo oni.
Gbogbo ire gbaa tioba wa nile aye.
Wa fun mi ni temi. T'aya-t'omo t'egbe - t'ogba, wa fi yiye wa. Ki o f'ona han wa. Wa f'eni - eleni se temi.
Alaye o alaye o. Afuyegegege meseegbe.
Alujonu eniyan ti nf'owo ko le.
A ni kosi igi Méjì ninu igbo bi obi.
Eyiti o ba ya'ko a ya abidun-dun-dun-dun.
Alaye o, alaye o.
Àse.- Reza a Olódùmarè
Inscreva-se na nossa Newsletter para ver novas fotos, dicas e postagens do nosso blog. Não se preocupe, nunca enviaremos spam para você.