Festival de Ifá foi um sucesso, contamos com a presença do Oba (Rei) Aare Ogboni Igba Iwase Agbaye,de Ilé Ife, Nigeria, Baba Elegun de Nigeria. Devotos e filhos de Ifá do Brasil todo.
Olódùmarè, mo ji loni. Mo wo'gun merin aye.
Igun'kini, igun'keji, igun'keta, igun'kerin Olojo oni.
Gbogbo ire gbaa tioba wa nile aye.
Wa fun mi ni temi. T'aya-t'omo t'egbe - t'ogba, wa fi yiye wa. Ki o f'ona han wa. Wa f'eni - eleni se temi.
Alaye o alaye o. Afuyegegege meseegbe.
Alujonu eniyan ti nf'owo ko le.
A ni kosi igi Méjì ninu igbo bi obi.
Eyiti o ba ya'ko a ya abidun-dun-dun-dun.
Alaye o, alaye o.
Àse.- Reza a Olódùmarè
Inscreva-se na nossa Newsletter para ver novas fotos, dicas e postagens do nosso blog. Não se preocupe, nunca enviaremos spam para você.